Musics

Videos

News

Entertainment
PROMOTE MUSIC
ADVERTISE WITH US
Photo of 3 cats
Naija
Photo of 3 cats
Ghana
Photo of 3 cats
S. Africa
Photo of 3 cats
America

Happy birthday to taiwo and kehinde inakoju.

W3Schools

HappyBirthday to Taiwo and Kehinde inakoju

Happy birthday, Twins! May God fill both of your life with double blessings and wishing you two a very brighter life ahead! Twins mean double the joy, happiness and celebration. Sending heartfelt wishes two the most adorable twins ever born.

 

TWINS EUOLOGY/ORIKI IBEJI

 

Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún.

Ẹdúnjobí

Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi

Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà,

Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa;

Ó salákìísà donígba aṣọ.

Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá,

Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọ́mọ.

Wínrinwínrin lójú orogún

Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀.

Tani o bi ibeji ko n’owo?

Ẹ̀jìrẹ́ okin

Ẹ̀jìrẹ́ ti mo bi, ti mo jo

Ẹ̀jìrẹ́ ti mo bi, ti mo yó

Ẹ̀jìrẹ́ ara isokun

Omó édun nsere lori igi

Ẹ̀jìrẹ́ wo ile olowo ko ló

O wo ile olola ko ló bé

Ile alakisá lo ló

Ẹ̀jìrẹ́ só alakisá di alasó

O só otosi di olowo

Bi Taiwo ti nló ni iwaju

Bééni, Kéhinde ntó lehin

Taiwo ni omode, Kehinde ni ebgon

Taiwo ni a ran ni sé

Pe ki o ló tó aiye wò

Bi aiye dara, bi ko dara

O tó aiye wò. Aiye dun bi oyin

Taiwo, Kehinde, ni mo ki

Eji woró ni oju iya ré

O de ile oba térin-térin

Jé ki nri jé, ki nri mu

Ejire oyila winiwini loju orogun,

ejiworo loju iya re

Mba bejire mbayo,

O be kese be kasa,

ofese me jejeji be sile alakisa

o so alakisa di onigbaso,

okan ni mba bi mba yo,

sugbon meji lowole tomiwa,

Gbajumo omo ti ngba ikunle iya,

ti ngba idobale lowo baba to bi won lomo

Ejire ara isokun, edunjobi omo edun tin sere ori igi

 

Epo nbe, ewa nbe, aya mi oja lati bi ibeji

Taiyelolu ma yo se se,

Akehinde gbegbon

mayo se se

Ejire oyila, ema yo se se, nbabi edunjobi

mba yo pe mobi oba omo.

Edumare bawa da awon Ibeji wa si.

Amin Ase!

Charming twins

 

LIVE LONG AND NEVER SORROW

Yusuf Victor Oluwasegun Really cares about you guys….

 

 

Leave a Comment


Share this post with your Friends onNo Comments Yet

Leave a Reply


NOTE:- After Commenting, please wait few Minutes to get your Comment Approved!..


Pages: